ADUA ASINA OWO TODAJU
Lehin Irun Ishai lale ati ki ato ki Iru Azuba laro ao se awon Adua yii,
1. Solatul Fatih 100
2. Suratul Fatiha 100
3. Yaa Lateef 4,444
AKIYESI
TI abafe bere Adua yii lehin ti ati se Solatul fathi ati Suratul Fatia tan ao bere yaa lateef lati ibere ni ao maa saa waa si oke ni, bi enia ba file saa lati oke waale bi eni naa bani owo lowo, yio pada di eni ilele ni, ati isale lao ti !aa saa gun oke. E.g
Yaa Lateef 4000
Yaa Lateef 400
Yaa Lateef 40
Yaa Lateef 4
Ki ase be fun ojo meje, lehin Ishai ati Asuba, Olohun ni mofi Bura fun yin, Anu Olohun yio sokale ki oto di ojo keje koda ale !a ri aye se iyoku mo sugbon ki a gbiyanju ka pari Adua yii.

Walai confirmed ni adua Yi
ReplyDelete