Wednesday 6 September 2017

ASEJE OWO TODAJU
Ao han Suratul Wakiah 313, ao wa afomo iyalode funfun tutu 313 ao maa han Yaa Fatahu si ara ewe kokan, ao waa lo ewe yii kuna daadaa pelu iyere die, tabi ata, ao ge Eiye Etu si iyekiye, ao se laseje pelu hantu Wakiah yen, gbogbo elo obe lao fisi, bi magi, iyo, epo.ao pea won Alfa ki won round wa ao joko si arin won maa je asejeyen, won yio maa bawa saa Suratul Wakiah 313, ti won baa ti nsa ao maa je aseje yen. Ki ato je ao ti so eran agbo funfun kan si ita, kete ti won baa pari Suratul Wakiah tan ao pa eran yen fi se sara. Ao ri Buaya owo lodun naa.



TI AWON ENIA YIO FI MAA FERAN WA
Ao wa Ewe Bomubomu iye Addad Suratul Yusuf, ao maa han aya kokan si ara ewe kokan, ao saa ko gbe daadaa, ao gun pelu, gbogbo owo ti a naa ni ilu ti a waa, Ewe anu, ewe orijin, irun abe obinrin die, ewe akonimora, imi ojo ati afoku glass die, ao gun kuna, ao maa fin ni araro ao si maa saa suratul Yusuf eyo kokan ni igbati a baa nfin, ao maa duro ninu efin turari naa ni, odaju pupo Koda bi enia baa ni eran ikorira lara ti o baa nfin turari yii, awon enia yio maa feran re.

OSOLE OWO TODAJU
Igunugun tonifun kan tabi oye kan olongbo dudu kan eyele funfun kan okete aye kan akuko adie funfun kan abo adie funfun kan iye agbe mewa iye aluko mewa ikode mewa itun pupo ifa pupo eso abeere pupo ori abo aja tutu ewe ogbo ewe apada ewe owu akese ewe eyinbisowo odidi atare kan aofi eyin igun lenu agbada ijogun aoko awon eran yokusi katowa fi ewe bolori aojo po aoro sinu sere ao mafi fokomu lojojumo

ILIAMU TABI ISOYE TODAJU
 Eye awoko kan Eye oloburo kan aye akoko kan Eye ibaka kan ewe ojiji ewe oniyemiye ewe iyeye kuluso 22 aojo papo aomabu ebu yan die die latifise obe akuko toti kojayekoja orun lepo niyo aosi je gbogbo re tan patapata

1 comment:

  1. Best Titanium Blocks | Titanium Blocks | TITanium Art
    Tito is the ford focus titanium hatchback first-ever device by TITIC to utilize a design of a block. The price of titanium Tito Block design enables users to titanium gravel bike create blocks as a titanium exhaust wrap way to $1,899.99 ceramic or titanium flat iron · ‎In stock

    ReplyDelete