Sunday 24 September 2017

ORORO IPARA ANU TODAJU
Ao gun ewe imunle die, ewe lapalapa funfun die, ata ijosi meta, epo obo die pelu epo igi nla die kuna daadaa, ao daa sinu Olive oil ao da lofinda orisi meta si die die, ao maa fi para, Odaju samu

Ewe Nje (B E N) Zones
Aki gbogbo awa Zone kokan ni ipinle kokan wipe aku dede iwoyii, Olohun ko ni jeki emi ati eyin waa wo iran laye, gbogbo waa pata lao gbe rere se laye. Amin.
oro wa da lori awon zone kokan ti a ti gbe kale ni ipinle kokan ni all over the world, laipe yii ao maa mun date ti afe gbe meeting ojukoroju kale ni ipinle kokan, Ninu Meeting yii ao ko Form Egbe waa si Zone Kokan, ki gbogbo Awon ti won baa fe ko ipa ninu Meeting yii toju 2 copies of there Passport, okan yio wa lori form ekeji yio waa fun Membership ID card.
Lagbara Olohun ki Ose yii topari ao maa Announces Agbegbe ti ati fe bere Meeting yii ni ilu Eko. Anfani po pupo lori meeting yii, Opo Enia ni won nilo awon asiri kan toje wipe gbogbo ibiti won baa de lati gba awon iru asiri yii EBU ni won ngbe le won lowo pelu owo topo, mofi Olohun Bura meeting kekere ti ase ni arin ara wa lana, Asiri orisi 35 ni mo gba ni Ano lowo awon External people ti won je agbalagba ti won bawa joko meeting lana, ti asi tun dan bi Mefa wo lana yen naa, koda lara awon asiri kan ti a ri gba ni wipe
BI ONA BADI TI AIYE BADE OWO ENIA
Epo Obo, ao gun kuna ao fi iyo po papo, gbogbo eniti o baa nso wipe ogun agbana nda ohun lamun etc ki abu die si owo ki amaa fi owo keji raa titi yio fi wo ile
ninu awon Asiri ti emi tun rigba lana
1. Ado Atona todaju yato si eyiti won maa nfi Owo gbesoke, ti won o ma paro wipe o dide fun ara re, koda atun danwo lana tosi daju
2. Ogun Atude todaju,
3. AKOYE ASASI todaju
4. Ipese Ado gbe Adomin Eiye wonu Eiye
5. Olugbohun ti won ma nfi npa Adie, tabi anything koda o le pa Malu, omo odo agba iba yin o
6. Awon Isora lorisirisi
walahi o ku die bayi ao baa gbagbe wipe awa se meeting lana toripe gbogbo awa ti a waa ni meeting lanaa ntu ara sile ni, inu awon agbalagba to wa pelu wa ndun ni, ti won nsi ndan ise wo fun waa, Ha! asiri nbe, koda molero pe awon baba waa ti gbe agbara lo tele ni, asiri nbe.
nidi eyii inu wa yio dun bi ebaa le darapo mo egbe Ewe Nje (BEN) Tokan tokan.
Ewe Nje BEN
kunfayakun

Saturday 23 September 2017

IRISI SURATUL YASIN TODAJU
Ao han Suratul Yasin eyo kan pere, sugbon ni eyin Ayah Kokan ao maa han Lakodijakum rosulu...... de ipari, be lao se han titi ao fi pari hihan re, ao fo ao waa ewe mafi owo kan omo mi, ao jo pelu Kalamun ti afi han Surah yii ati odindi ataare kan, ao waa fi hantu yii mun ebu yen lekan soso. bi ota baa pe one million ti won baa ti npe ori waa ni ibi beni ibi naa yio maa baa won lesekese, ti inira baa poju fun won, ti won baa jewo ese won ki adari ji won toripe bibe ko, eni naa yio ku ni. odaju. Ti abati mu hantu yii tan yio fe se waa bi iba sugbon kosi iyonu, ao gbodo lo ogun si ti ara waa baa nse bakan bakan toripe bi aba lo ogun si, Otaa naa koni ri inira kankan ti won baa nsa ogun siwaa, ti iniraa baa ti nba ota waa bi o baa lo ogun koni sise. odaju samu
ASIRI TI A NFI NKO ILE SI ORI ILE
Asiri ni eleyi ki se ogun raaraa, asiri sini baba ogun koda iyalaya ogun, Afi ele ki gbogbo Awon Admistration egbe Ewe Nje pataati ni ilu nla mejeji ti atise Meeting loni, apadabo meeti9ng waa yio jasi irorun fun gbogbo awa ti awaa ninu group yii pata.
Ao waa Ile ikan to gaa daadaa, ao ge ori ile won waa si ile ao fi omi po ko ki daadaa, ao waa eyin ororo meta, ao fi iyepe ikan yii mo ara eyin meteta ti aye kankan ko gbodo han sita raaraa, ao gbe lo si ori ile naa ao gbe ile naa ko jin die, ao waa gbe ohun ti amo pelu ile ikan yen si inu koto naa, ao waa baa wi gbolohun wipe
OHUN RE
Ati ojo ati erun ni ikan nmo ile tire, ki awa egbe ewe nje tokan tokan ko ile wa ni odun yi ni kia kia, toripe, omi ki po lojo ki ikan maa mo ile tie, ki asiri awa omo egbe yii bo ni kia kia ki affi ko ile yii ni kiakia. ao waa bo mole,
walahi ko ju baayi lo, pelu Ogo Olohun Ao ri owo ko ile yii nji kia kia,
ti ko baa daa yin loju, Efun mi ni 4 plots ninu ile yin ki ndan asiri yii wo ni ibe hahahaha odaju walahi

Wednesday 20 September 2017

ADURA TIAFINKOJU EYIKEYI ISORO YALA OGUN OTA, OGUN IDILE, ABI EYIKEYI OGUN AIFOJURI TONBA OMO ENIYAN FINRA TIKOJEKI ONI ILOSIWAJU NINU IRIN AJO AYEERE
TI OBATI JA EWE TOSITI WA EGBO TOJEWIPE OJU KAN NAN LONJASI, IWO OMO IYAMI DAKUN NI IGBAGBO KOSIGBIYANJU ADURA YII WOO HNMM NINU EPE NINU ADURA WAASEKAN
Aowa aso pupa, aoran ni deede sokoto ewu, ati fila, tobawadi deede agogo mejila abo oru (12:30a Aose Aluwala Aoyan
Nafilah Rakah 2, Fathia 99 Lori iduro kookan, aonikaa surah kankan leyin re, aowa salamo, sugbon origun mereerin laoyan nafilah meji meji yen sii, aomaasalamo ni origun kookan, leyin salamo aodojuko kiblah (gabasi) aomu tesbah aose
ISTIGFAAR........1000
ASALATU ALA NABIYYI........1000
HASBUNALAH WANIMOL WAKEEL........4
050
Aodide aolosun, aosebee fun ojo meje, leyin ti ojo meje bape..........Aodin akara elepo pupa, abi kapa adire akuko totobi daada, aofise sahara,
hnmmm Ti oro eeyan kobatiidebi wipe kofeeni ojutu Mon kodakun komase iseyii ooo, bi iseyii se rora kere mon, wonmanfi pa ota tobako tikofeejawo ninu oro aye yan nii ooo,,, aiye oni muwa o, gbogbo Lao segun awon ota wa ola anobi Mohammad,,, ameen.

Omo Odo Agba one

Wednesday 13 September 2017

ADUA FUN INTERVIEW TABI EXAMINATION 
Ao se aluwala, lori ijoko ekan pere ao saa يا ولي ١٩٩٩٩ ao ma sa Yaa waliyu 19,999lori ijoko ekan pere, ti aba ti pari adua yii ao pa akuko adie kan fi se sara, ojokojo ti aba ti ni exam tabi Interview ao maa saa Yaa Waliyu 150, ao si tun se sara lehin exam tabi Interview naa
TURARI TI A NFI NSE ADUA FUN AWON ENIA TI WON WAA NI OKERE
Oga gbigbe 16, iye agbe 16, iye Aluko 16, ikodie 16, iye lekeleke 16, Ewe pawondaibida sobi dire ao gun papo daadaa, ao ko won sinu aso funfun, ao waa jaa ewe lapa ti kolu 16, ao han Suratul Fatiha kokan si ewe kokan, ao jaa ewe Bomu bomu 16 ao han Suratul Fatiha lati oripodi si ewe kokan, ao gun mejeji po pelu imi ojo die, ati etu ibon die, ao saa si ategun, ao waa da mejeji papo, ao ro papo daadaa, ao da si inu apo aso funfun ko gbodo kanle mo, ao maa fin ninu ina laro kutu kutu ti aba fe fi se adua fun enia ti ona re ba jin,

Ao waa Apere kan, ti aba ti fin turari yii ao da apere yen bo mole, ao waa joko si iwaju re ao maa saa Suratul Fatiha 92 ti aba saa tan ao si apere yen ao waa toro ohun ti afe fun eni naa. Lagbara Olohun Adua naa yio gba ni kiakia.

Sunday 10 September 2017

Eleyi ni lati so fun gbogbo egbe pata wipe, Egbe Ewe Nje (B E N) maa hold online seminar ni Ojo kewa Osu kejila ninu Odun ti awaa yii.. Online Seminar yii, ao se Awon Ogun won yii si Odindi iwe kan ti yio je PDF, ninu Iyara waa yii lori Website waa ao create private room kan ti ao invite gbogbo awon ti won baa san owo Iwe yii, ti olukaluku won ti won yio ri iwe won lati download tabi ki won print re lati inu private room yii..... Eleyi atun reduce owo transportation awon ti ona won jin, owo iwole inu online seminar yii je N2500 only, gbogbo eniti o baa ti san owo iwole yii, ki won send oruko ti won nje lori facebook siwaa immediately ati oruko ti won fi san owo lati le ko oruko won sile ni kiakia. Online Seminar yii yio waye ni 10 of December 2017, lehin Seminar gbogbo eniti o baa fe ra iwe yii ao taa ni N5000. Eleyi ni die ninu akole awon Ogun ti o maa waa ninu iwe Online Seminar wa

Awon ogun ti afe so sita leleyi
1. Oruka ti yio maa gbona mowa lowo ti walah baa fe sele, (Boya ninu motor ni o tabi ibikibi)

2. Iwosan Stroke 1

3. Hypertension 1

4. Diabetes

5. Jedi jedi 1

6. Mayehun ti a ma nfi gba ohunkohun

7. Iwosan Inu rirun 1

8.Idiyiyo

9.Ki Inu maa run Obinrin Lasiko nkan osu

10. Atosi ojo pipe 1

11. Awure Todaju 1

12. Osole three in one

13. Onde Iriran

14. Olugbohun Awise

15. Asiri Agbara lati ba Aljanu soro ti ao si maa bi lere ohunkohun

16. Ulcer 1

17. Iwosan Warapa 1

18. Epe todaju

19. Gbetugbetu todaju

20. Ilaya ki jinijini mun ota waa ti won ba ti ri wa

21. Sigidi Akoya

22.  Flusher gbogbo Arun include HIV or Aids

23. To reduce Fat

24. Iwosan Iju todaju

25. Iwosan Eti riro

26. Iwosan Ropa rose

27. Iwosan Ropa rose tosese bere

28. Aseje Iwosan Stroke

29.  Iwosan Iju totipe

30. Iwosan ti Ese bawu

31. Apa Oro Ofa larq

32. Iwosan ti Eje koba daa lara Obinrin lehin ibimo

33. Atosi olojopipe

34. Iwosan low spam count

35. Iwosan Appendix

36. Iwosan Were

37. Iwosan Ropa Rose ti oti gbe enia lule

38. Iwosan high blood pressure

39. Iwosan Beli beli

40. Iwosan Ogbe Inu eleje

41. Inurirun olojo pipe

42. Iwosan Sickller

43. Awoka Todaju saka

44. Agbo HIV or Aid Ewe NJE (BEN) heal the world

45. Iwosan Inarun buruku

46. Agbo Tude todaju

47. Iwosan Iba Typhoid

48. Iwosan Maleria

49. Iwosan Iba Jedo jedo

50. Iwosan Ori fifo Tulu


Gbogbo Eniti Eto yii koba yee Edakun Epe Enia kan ninu awon Administration lati se alaye fun yin lekun rere
Eco bank
100300353464
Diamond Bank
0062353464
Account Name Musediku Adeola Mumuni

Friday 8 September 2017

ASIRI SURATUL FATIHA
FUN AWORO
ao han 41, ao gbo ewuro pelu omi ao fi fo hantu yii ao daa sinu ado ato ao daa iyo ati ori si, ao so ko si enu ona waa odaju

FUN ASINA TODAJU
Ao han ni igba 313, ao fo si ibi kan, ao waa ewe Ela die, Ewe Awerepepe die, ao lo pelu iyere die, ao fi se Ahon malu tage si mesan je fun Okunrin meje fun Obinrin, Ti aba ti fe je ki ato je eyo kan ninu ahon yen, ao ka Ipari Suratul fatiha lemeje, صرطالذين انعمت عليهم غير المغضوب عليهم ولا الضل لين be lao se maa kaa titi ao fi je tan

FUN KI OWO MAA WON WAA
Ao han Suratul Fathia 41 si opon ola ni igba Meta 41x3 si ike ototo, ao waa igbin to tobi meta, ao fi okan se igbin yii pelu eyin meta. Ti o ba jina, ao w ewe aje die, ewe Orijin die, ewe awerepepe die gbogbo ewe yii gbodo je ojoo, ao lo meteta pelu ata ijosi die, ao wa fi hantu keji se awon igbin ati eyin ye je lodidi ni o, iyo epo gbodo wa ni ibe, ti o baa jina ao koje ao waa mun eleketa le lori. Odaju
ASEJE BIBO ASIRI NI KIA KIA.

Ao wa ewe tangiri oojo 16, ao wa ewe ola die, ao wa iyere 16, ao lo Gbogbo re papo, ao wa fi din eyin adie agric meta lepo niyo, tio bajina ao so kale Ao je kio tutu ao Se adua si, ao waje Walah talah o yara sise fun oni gbinyaju eniyan
OGUN ARISIKI
ti ono ore ojiji fimasi fuyan feniti gbogbo oro re tisu tan patapata-ori oka 16 ati ori ere 16 ati atare Nla 16.ao PA eye igun aye silori ninu ikoko laijeki enikan riwa ni ikoko. Aowafi igun yen bo mole ninu ikoko aojo. Lilo re-ao Mada pomo oyin ati oti papo aowada ebu yen fi miss e. Lilo pelu Adura.sugbon aose ipese tiaba lagbara kiato bere Lilo re. Walai odaju. Texted and confirmed by omodo agba. Ewenje Ben world wide kunfayakun olohun ni. Esiku ojulono online seminar WA tio nbo lono laipe ki oluwa bomi lasiri kinri owo temisan o
OLUGBOHUN RIRISE TODAJU
Ako ewe mereerin (ewe ina ewe esisi ewe aragba ati ewe oloyin) aogun po mose dudu aofi emu aila pelu oguro aila po papo pelu oti schinap po Papo dada aofi oga aye ati eja ojiji aye kan tele iho malu yan aowa ko ose yan lelori aofi aso pupa bo lori ao we mo lara aomasin aso pupa yan loju re ti abafelo ao kan ma se hahaha lemeta si ni aose adura ikan ti abafesi

Thursday 7 September 2017

OLUGBOHUN TODAJU

Ao han Suratul Yasin meta, okan Ariran, Okan Afoju, Okan Aditi, sugbon gbogbo igba ti aba ti de ibi ini amantum birobikum huntsman ao maa para ibe ni igba 1111 ti o ba ti pe 1111 ao waa pari Surah naa, ao fi omi die fo hantu kokan si aye ototo. Ewe Ogbo ti ko luju 21, ao han Yaa Jabar si ewe kokan ao sa kofi gbe daadaa ao gun kuna aopo pelu ose dudu ti o le gba inu iwo Malu kan, ao fi omi hantu Ariran po papo daadaa ao tun fi Ariran naa po daadaa, Lehin naa ni ao fi Aditi po daadaa ao gbodo fi gbogbo re popo lekan soso ao to tele ara won bi ase ko si ibe ni.ao fi odindi Ataare kan, ati Ako okuta meta sinu iwo malu yen, ao ki oga oye bo ti yio gbe ori soke, ao ko ose yen le lori, ao fi aso pupa bo lori,, ao gbe si ori ajah fun ojo meje, lehin ojo keje lao to de ibe lo mun, lati igba ti ati lo gbe si ori ajah yen lao ti maa saa  ini amantum birobikum huntsman 1111 fun 7 days ti aba pari re lojo keje, ojo kejo lao le gbe kuro lori ajah ao gbe wonu ile ao fun ni oruko ao si baa se adehun wipe Ti mo baa ti pe Oruko re ni ki o to jemi oo, ao fun loruko naa, ti a baa ti fe lo ao pe oruko re lemeta ao fi ahon kan ao so ohun ti aba fewi. Odaju


ise yii waa lati odo shaik mi, Al Bayanah ni ilu ninja

ILEKE ADODUN
Ao jo ori oka toni ase lenu kan pelu ewe ominsinminsin gogoro ati pelebe ati atare odidi kan, ao wa agbon kan totobi dada toni omi ninu, ao wa fi omo inu agbo ye gbo ewe mejeji ye again, ao wa da ebu ye sinu egbon ye, ao ki eleke bo, ao wa da omi agbon ye si ninu, ao gbe pamo fun ojo meje, lehin ojo keje odi lilo sidi fun obinrin
OSOLE OWO
Ori aparo meje, ori eye etu meje, eye otata kan ati eye kowe kan, ao ko won sinu ape, ao wa ja ewe ajaobale ojoo bo mole, ao wa jo pelu odidi atare meje, ao mafi oti schnapp lo laro laro.
EYONU ASINA OWO TODAJU.
Alangba ako mesan, abo alangba meje, ao du eje penpeye ako kan sinu ape tuntun, ao wa la inu penpeye ye, ao ko awon alangba ye si ninu ati odidi atare kan, ao ran pa pada, ao gbe sinu ape, ao ko ewe ajaobale tutu ati ewe orijin tutu bo lori mole, ao jo papo, ao mafi mu eko gbigbona pelu orii ati oyin.
OSE ASINA AWON AGBA TI ONA BADI, TI AO RI OWO NA................ao wa Ako alangba meje, Abo alangba meje, eye ounbe meje, esuru pupa ao gesi meje, odidi atare meje, ao jo papo, tia bajo tan ao lo ti yio kuna daada, ao wafi adin dudu pomo Ose, ao mafi omi gbigbona we laro laaro(odaju)
ISE YII JE ISE NLA TI O MAA NTUN IGBESE AIYE ENIA SE


Ejinrin tutu, adie abo toti bimo ri dudu, eyin adie ibile 16, atare odidi 16, eye onbe 16, iye igun 16, ewe ako rere tojo, ewe bomubomu ati ese re topo tojo, eye kowe meta, aso awon agba meta, aso egungun die, egbo tude topo, epo obo topo, igi nla topo, itanna ibepe ako topo tojoo, ao ko gbogbo won sinu ape, ao wa du eje penpeye ako funfun si lori, ao wa gbe kana, ao fi epo pupa yipo aro, taba jo tan, ao Di mo aso egungun tabi aso dudu, funfun, pupa, ao so ko soke, ao wa mafi epo pupa LA lalale, oti lo laro laro.


ASIRI-IJINLE-TI A FI NPINLE-OLA-TI A FI NRAYE GBE FUN ENIYAN-ti iru enibe yio sini opolopo-owo ati ola..tested an confarm. ti a bama se ise yi-a o han psalm-72 sinu opon-ola pelu tada ti awon musulumi fi han hontu fun odindi ojo meje bere ni ojo monday titidi ojo sunday-e o ma jo hatimi talsman ti a npe ni-solomon weath seal-meta si ni ojojumo yio je pe seal yen 21 ni e o lo fun ojo meje yen,e o ma mu lojojumo ki e to je ohunkohun-ti o bawa di ni ojo keje-e o pa eran-agbo funfun balau kan-amon e o ti ra eran yi sile ni ojo satide,ti e bapa eran yen tan.e o yo okan re-e o fi eran toku se sara fun awon eniyan tabi ki e gbe lo fun awon onibara-e o wa ojuda eyele funfun kan,gbogbo owo ti a nna bere lati 100 to 1000,owo orisi ilu meta.pelu solomon wealt seal meta toku,e o jowon papo.etu won ni e o wafi se okan eran-agbo yen-psalm 72 ti e bahan yen nani e o fi seje-eni tose ise yi gangan yio si nukan je ise yi ni inu iyara ni onu nkan pelu aso funfun lorun-lati ale ojo ti eni na bati je ise yi ori ibusun,

aso ti yio fi ma bora,ati aso ti yio mawo jade gbodo je funfun..atipe enikeni ti yio se ise yi gbodo to omo 35-years.ise yi daju ju ada lo-asiri yi ni a npe ni-lukudi-imule-aje-funfun- etutu re-igba-meji lodun ni a nse etutu ise yi-ojuda eyele funfun kan solomon wealt seal meta ati 1000,e o jo seal yen ati owo yen papo-etu re ni e o fise eyele yen je.. ewo re-a ki nna owo yi si oju-ona agbere-beni e gbodo mafi owo ati ola ti e bani se anu ati iranlowo fun aimoye opolopo awon eniyan-beni owo yi ki nse owo ti npadj parun-beni kodin ojo ori eniyan kuru-kosi bere eje lowo eniyan rara- fun-itosona-e le kan simi-


OSE ITAJA
o yara mu owo wa- ewe sinkirinmini oojo,eyin adie ibile eyo kan,iyo olokun die, pelu ose ganna- sise re-e o gun ewe yen ati eyin adie yen tepotepo ati iyo papo mo ara won-e o gun won mose e o fi ojulowo oyin po-e o ko sinu ike ff-lilo re-e o ma we ni ojo metameta

ASIRI KI ALE RI OWO FUN INAWO..
e o lowa ojulowo efo gbure oojo,e o gun po mose dudu tabi ganna,e o wa da ojulowo etu-ibon oyin le ose yen lori-e o wa fi o wo mu ogunna kan ti ina wa larare daada-e o ju sori ose yen-toba ti wa gbaa na,e o sese tun wa fi o wo po won po-e o ko sinu ike- lilo re-ti inawo baku ojo meje tabi ojo merinla-ni e o ti bere sini we ose yi-o da ju a o ri owo fise inawo wa..

Wednesday 6 September 2017

IWE EPE DANU
Efun die, Osun die, Edu Die, ewe awerepepe ojo, ao koko gun Efun loto, Osun Loto, edu loto, ao waa gun Ewe awerepepe pelu ose dudu, ao fi owo mun Ogun ina si ao gun po, ao waa da osun si ao po po daadaa, ao tun Efun si ao po po daadaa, ao waa da edu si ao po mo ar won daadaa, ao ko sinu ike kan ao gbodo gbe si inu ile o, eyinkule ni ao ma gbe si, ti aba fe lo, ao bu die ni ibe lo si odo, ao ko eyin si ibi ti odo ti nsan bo ao koju si ibiti omi naa nsan lo, ao maa we.

Ao fi iyere Osun te ifa Ejiogbe ao waa pe ohun si bayi,

Ohun re
Para Pahun 3x
Oju Orun o lenini
Adifa fun Orunmila nigbati o nti ikole orun bo wa si ikole aiye, Won ni ile aiye ti o nlo yi, awon Elepe nbe nibe, Awon alasasi nbe nibe, Awon Alasan nbe nibe awon Alfa, woli Babalawo ika nbe nibe etc oni toba se bi ise temi Lagbaja omo Lagbaaja ni oni
Efun ni nba aiye osun je
Osun ni nba aiye efun je
Ati efun ati osun Edu ni ba ye won je
Gbogbo epe won lori emi lagbaja Omo Lagbaja ati efun ati osun edu ni nba aiye won je, ki gbogbo epe ori mi asasi ori mi, asan, epe idile baba, epe idile iya etc Ati efun ati osun edu ni nba aiye won je.  Toripe enikan ki se ina koma le joni, Awerepepe ooo, Epe idile baba epe idile iya, Epe ota lori emi lagbaja omo lagbaja ki o waa pe gbogbo e danu lori mi lati oni lo, odo ki san kobu oju wo eyin... Adua, ao waa daa mo ose eyiti abu ti afe lo wa yen, ao lo we.


IKILO
ti aba fe lo we aso ti awolo ao gbodo wo pada wale mo, ao si gbodo wo eyin titi ao fi dele, Ojo meta lao we ose yi lera lera, Odaju

PENIS ENLARGEMENT  (KI OKO LE GUN DAADAA)
Ao lo be Ogede Agbagba ti koti ni omo lori, Ao beni arin, Eyiti o baa tun nyo ni arin re ti a ti ge (Abeyo) re, ao jeki o yo de dede size unkan omo kunrin ti a nfe, ao tun lo ge sonso mariwo ope ni nize ti ogede ti a ge yen, ao gun won kuna daadaa ao fi odo irin gun ko kuna daadaa, toba wuwa ale sa si orun ko gbe daadaa ki a tun tun gun daadaa, ti o baa si wuwa ale gun ki a lo beyen naa, ao fo eyin ororo kan si, ao fi po ori ao ma fi wo Oko naa lati Oke wa sile, ao gbodo fi wo lati isale waa si oke o.

Akiyesi ni wipe, ti o ba jepe asa egboigi yen ni, ti aba ti fe fi po ori ao fo eyin kan si ao fi po pelu ori, Odaju 

ASEJE OWO TODAJU
Ao han Suratul Wakiah 313, ao wa afomo iyalode funfun tutu 313 ao maa han Yaa Fatahu si ara ewe kokan, ao waa lo ewe yii kuna daadaa pelu iyere die, tabi ata, ao ge Eiye Etu si iyekiye, ao se laseje pelu hantu Wakiah yen, gbogbo elo obe lao fisi, bi magi, iyo, epo.ao pea won Alfa ki won round wa ao joko si arin won maa je asejeyen, won yio maa bawa saa Suratul Wakiah 313, ti won baa ti nsa ao maa je aseje yen. Ki ato je ao ti so eran agbo funfun kan si ita, kete ti won baa pari Suratul Wakiah tan ao pa eran yen fi se sara. Ao ri Buaya owo lodun naa.



TI AWON ENIA YIO FI MAA FERAN WA
Ao wa Ewe Bomubomu iye Addad Suratul Yusuf, ao maa han aya kokan si ara ewe kokan, ao saa ko gbe daadaa, ao gun pelu, gbogbo owo ti a naa ni ilu ti a waa, Ewe anu, ewe orijin, irun abe obinrin die, ewe akonimora, imi ojo ati afoku glass die, ao gun kuna, ao maa fin ni araro ao si maa saa suratul Yusuf eyo kokan ni igbati a baa nfin, ao maa duro ninu efin turari naa ni, odaju pupo Koda bi enia baa ni eran ikorira lara ti o baa nfin turari yii, awon enia yio maa feran re.

OSOLE OWO TODAJU
Igunugun tonifun kan tabi oye kan olongbo dudu kan eyele funfun kan okete aye kan akuko adie funfun kan abo adie funfun kan iye agbe mewa iye aluko mewa ikode mewa itun pupo ifa pupo eso abeere pupo ori abo aja tutu ewe ogbo ewe apada ewe owu akese ewe eyinbisowo odidi atare kan aofi eyin igun lenu agbada ijogun aoko awon eran yokusi katowa fi ewe bolori aojo po aoro sinu sere ao mafi fokomu lojojumo

ILIAMU TABI ISOYE TODAJU
 Eye awoko kan Eye oloburo kan aye akoko kan Eye ibaka kan ewe ojiji ewe oniyemiye ewe iyeye kuluso 22 aojo papo aomabu ebu yan die die latifise obe akuko toti kojayekoja orun lepo niyo aosi je gbogbo re tan patapata

Tuesday 5 September 2017

IFERAN GBOGBO ENIA TODAJU
Ewe Awerepepe, ewe Taba ibile, Igbo mimun, ori ijapa, ao gun kuna daadaa, ao da sinu lofinda eyikeyi ao maa fi paa oju tabi gbogbo ara. Awon Enia yio maa ni ife waa pupo
ASIRI TI A NFI NDI ENITI NKOLE LAYE
Ao waa Image candle ako fun Okunrin, Abo Fun Obinrin, ao fi si abe Pillow waa fun 7 days, Irun ori waa ti afa lafa tan, Ewe Pawon da sobi dire, Ewe Apada, Iye Agbe meta, Iye aluko meta, Iye Odidere meta, ao te aso funfun ilaji opa kan sile, ao ko gbogbo awon unkan won yii sii, ao di papo, ao jo pelu odindi atqare kan, ao lo kuna daadaa, ao po lose dudu, ao fi Odindin oga  Aye kan ati Image candle yen sinu igba olomori ki ato ko ose le lori, ao waa lo fi owo (Money) ara waa raa Block eyokan pere ni odo awon ti won nta blocks, ao gbe block yii wole, ori block yii lao gba ose yii le, ose yii ko gbodo kan ile ti aba ti ko sinu igba yen,....

Emeta lari Ose lao maa fi we, Aro kutu kutu ni wiwe re, Gbogbo unkan Ebe Agba ni ki Ese ki won maa baa dawole ose naa, Walahi bi Omo Odun Merindinlogun ba we, Yio ni ile lori

Ki elo awon unkan ebe agba daaadaa awon Ipese Ebe Eleiye ki ebale ba iyonu won pade lori ise yii... Boya won a bun e nile ni o tabi ki o raa ile, okan aje okan ninu re.

Ti eba si nfe orisiri Ipese Lolokan kojokan e kan si waa lori ero ibani soro waa, ki e bere fun Iwe Volume  Two waa, N6000 pere ni owo iwe yii, awon Ipese lorisirisi po ni ibe
1. Ipese Ebe Agba
2. Ipese Akoya
3. Ipese Ebe Eleye meteta Dudu, Pupa, Funfun
4. Ipese Arisiki
5. Ipese Ajantuka
6. Ipese Iferan
7. Ipese ti a nfi ngba aso Agba
8. Ipese Ibawi
9. Ipese Itaja
10. Ipese ki Ogun ma je lara waa
Etc

Monday 4 September 2017

IWE VOLUME ONE ATI VOLUME TWO
A nfi asiko yii so fun gbogbo wa wipe, Iwe asiri ogun lorisirisi ti egbe Ewe Nje gbe kale ti waa ni oja bayi,

1. Volume one N5500
2. Volume  two N6000
 Awon Orisi risi asiri leo maa baa pade ninu iwe yii. Fun ekunrere alaye, elepe awon number won yii

1. 07037422552
2. 08034151751
3. 07067124318
4. 08125703383
5. 07066504892
6. 08038081390
7. 08110206078



AWORO TO DAJU

Ao waa candle funfun 16 lona marun, lara candle kokan ao maa fi Abere han Ayah yii si gbogbo ara candle kokan ti aye Kankan koni han lara candle naa, Inahu ala rojeehi lakodiru, ao han si gbogbo candle yen lara pata, ao waa di 16 papo pelu owu funfun, ti yio fi je 16 lona marun, ao waa ako alangba marun. abo naa marum, alangba naa je mewa pali Sugar st Louis kan, ao gbe ile si igun mererin aye ti afe gbe ise yii si ati arin gbungbun aye naa, ao fie yin Bobo kan lele, ao da ponri de lori, ao gbe candle yen le won lori loro ti yio koju si oke, ao fon suger St Louis 16 si inu koto naa, ao daa iyo cup kan si pelu oyin agolo milk kan, be lao se se si gbogbo igun iyoku ao se be naa ni arin, ao waa bo si egbe igun ibiti a ri unkan yen mo ni egbe otun, ao pe irun Azubah toni ASOLATU KHERU MINA NOMI si igun akoko, igun ekeji ao pe iru ago meji si, igun eketa ao pe irun ago merin si, igun ekerin ao pe irun ago meje si Igun Ikarun ao pe irun ago mejo si, ti aba ti fe maa pe irun kokan ao maa daniyan irun ti afe pe, ti abaa ti npe irun kokan ao maa bo si arin ile ti a ri elekarun mo ao maa se IKHAMO ni ibe, ti oba dori irun elekarun, ti aba tip e tan ao se IKAMOH ao waa da iyepe bo won mole.Bi ogo baa nje ti Olohun ti won baa ti npe irun kokan laye beni Olohun yio maa dari awon enia waa raa gbogbo ohun ti a nta. Iru aworo bayi daa ni aye ti won baa ti nta Ounje,Oja, Ile ise Nla, EtC