Thursday, 7 September 2017

OSOLE OWO
Ori aparo meje, ori eye etu meje, eye otata kan ati eye kowe kan, ao ko won sinu ape, ao wa ja ewe ajaobale ojoo bo mole, ao wa jo pelu odidi atare meje, ao mafi oti schnapp lo laro laro.

3 comments:

  1. eseun sir olohun a je ki a ri Yin pe

    ReplyDelete
  2. Bawo ni owo no shé màwà

    ReplyDelete
  3. Thank You and I have a keen give: Where To Remodel House for home renovation

    ReplyDelete