Wednesday 25 October 2017

EBE AWON AGBA TODAJU

Ao waa epo obo aso fun fun ilaji opa, ao te aso yen sile, ao ko epo obo le lori, owo eyo 16 ti koluju le lori, odindi ataare nla kan le lori, ao lo ri mo oju ona ti won ngba daadaa fun ojo meje, lehin ojo keje ao jo, ao lo kuna, ao ma fi epo pupa la ki ato sun ni ale,

AKIYESI
Ti aba ti wu kuro ninu ile, ao ka iye owo eyo yen, ti o baa pe 16, ise ti sese ni yen sugbon ti ko ba pe 16 mo, ao gbodo lo mo ooo, oni ewu ti aba lo oo, ao lo ko danu ni