Monday 4 September 2017




ORO NIPA IRAWO ATI OHUN TI O BAA IRAWO OLUKALUKU MUN LAYE
Opo Obi loti da igbese aiye omo re ru nipa pe dandan ise bayi bayi ni o gbodo ko, Olukuluku eda ni Olohun ti fun ni ise ti yio maa se laye, sugbon latari agidi ti awa omo Eda Adamo ni koje ki a ni ifura. Oro Olohun ko le ye omungo Eda sugbon Ologbon eni ni nye, Opo ti o yeki o lo se ise Briclayer sugbon alakiyesi ko je ki o tete yan ise ori re layo, Eda ti o baa je omi laye ti o baa nse ise ina kole ni aluyo laye, eda to si je ina ti o nlo nse ise omi kole ni ilosiwaju laye. Imo nipa Irawo se koko laye awa omo eda, eleyi a jeki eda mo iru igbese aiye ti o le gbe, ohun ti oye ki a maa se ati ohun ti koye ki ase. Eda ti OIohun da lati ara omi ti o waa nlo se ise ni ile ise Bread, ki se epe raara kole ni aluyo laye. Ti abati bi omo Ejeki a gbiyanju ki a to awon to ni imo nipa Izab wiwo ki won se alaye lori Iru irawo ti omo naa gbe waa si aiye, iru ise ti ole se. Esu koni da irin Ajo gbogbo waa ru mo wa lowo laye. amin
I.                   Irawo ategun. Irawo Ategun je irawo to ni agbara pupo, bi walah batile po ju fun awon iru irawo yii igbeyin won maa nda pupo, won nma se orire lehin opolopo walahi,  oju awon iru eda bayii maa ni opolopo wahala ni aiye won, oju won ki gbe ibikan raaraa, ti won baa nse ise kan won atun pa ise naa ti won a tun gba ibi ise miran lo.

IKILO FUN IRAWO AFEFE
Oro awon eda bayi da gegebi eniti o ngbe kanga ti o waa de aye kan ti kanga yii ko waa kan omi, okuro ninu kanga naa, otun bosi ibo miran lati gbe kanga miran, be gege ni yio se maa gbe kanga yen lo titi ohun gbogbo ire yio fi tan mo lowo. Itumo oro yii ni wipe, Gbogbo igbati o baa ti gba ise kan mun mase maa kuro ni ibe ayafi fun idi kan

ISE TO DARA FUN IRAWO ATEGUN
Irawo Ategun gbodo je irawo to lo si school to keko gba oye (Graduate) idi ni wipe Irawo yii ohun ti won le fi jeun laye won ni Ise Akowe, iru won ni won maa ndi President, Governor  ati bebelo. Awon die ninu ohun ti omo irawo Ategun le se ni awon wonyi
1.   Mass Communication
2.   Publisher
3.   Alfa
4.   Pastor
5.   Advitisment
6.   Pilot
7.   Transportation
Gbogbo ohun ti o baa ti baa ategun mu laye

IKILO PATAKI FUN IRAWO ATEGUN
Irawo Ategun gbodo so ara gidigidi, Irawo Ategun gbodo je eniti o ntera mo Adura ni gbogbo igba, Ewe ati Egbo maa ntete je fun irawo Ategun ni idiwon ti won baa tin se adura daadaa, Irawo ategun gbodo munra si sise Ogun Isori daadaa, toripe won ki je ki won de ibi giga ti won nlo laye, Irawo ategun gbodo maa sora ni aye kaye ti won baa tin se epe pupo toripe Ada awon eda yii lati ara ategun, asasi ntete maa ja lara opo ninu awon omo ategun pupo, Egun idile baba nsaba maa nja iran omo ategun pupo ti ki jeki won tete de ibi giga ti won nlo laye. Kiyesi, Alakala bi ki won maa je ounje oju oru, tabi ki won maa ni ajo sepo ni oju oru.

2. IRAWO OMI
Irawo omi lagbara pupo, Asasi ki saba jaa won, sugbon egun idile baba nsaba maa nba won jaa pupo, Ewe ati Egbo ki sise lara won rara, Irawo omi ni obinrin iru won ni won ki gbe ile oko, won ki gbe ile oko toripe okunrin maa ngbe won ju sile ni, won a maa ni ewa pupo sugbon ogun promise and fail maa npo fun won pupo, Okunrin won maa nfie si ki won maa yan ale pupo.

IKILO FUN IRAWO OMI
Irawo Omi gbodo teramo Awon unkan isori pupo lati ibere pepe aiye won, Okunrin won gbodo sora fun isekuse toripe obinrin maa nda irin ajo won ru pupo toripe won nma nife si ale yiyan

ISE IRAWO OMI
Die ninu ohun ti Irawo omi le maa se
1.     Navey
2.     Seaman
3.     Doctor or Nurse
4.     Tita Eja tutu
5.     Pure water
Gbogbo ohun ti o baa jomo ise omi

3. IRAWO INA
Irawo ina je irawo to ni agbara ju gbogbo irawo lo laye, Sugbon bi won se buru to Omi ni nma nfa akoba fun opolopo won. Enia giga ni won pelu laye, Opo ninu won maa nje alawo pupa, Ewe ati Egbo ntete maa je lara won bi unkan ti won baa jo lori ina

IKILO FUN IRAWO INA
Irawo naa gbodo sora fun obinrin pupo, bi irawo ina baa se tan lati fe iyawosile o gbodo se iwadi daadaa toripe bi okunrin baa je irawo ina ti o baa le baa obinrin ti o je irawo omi pade, iru won ki gbadun ara won ninu ile, Omi yii sini yio maa paa ogo ina. Bi won baa ti njo ni ajosepo, beni omi yio se maa pa ogo ina re.

ISE IRAWO INA
Awon die ninu ise irawo ina
1.     Solider
2.     Airforce
3.     Tailor
4.     Hotel
5.     Caterer
Etc

4. IRAWO IYEPE
Irawoiyepe je irawo ti won nsaba maa ni oju anu pupo, won je eniti o le soro dada, won ni ogbon pupo, sugbon iwa igberaga nma nba ise opo won je, won feran iwa imo toto. Inakuna sin ma nda won lamun pupo

IKILO FUN IRAWO IYEPE
Irawo iyepe gbodo so ara won gidi gidi nipa ina kuna,  Bi suru awon irawo yii se po to be na ni ori kunkun won se po to nigbati o baa nbinu, sora fun inu fufu, sora fun iwa tara eni nikan.

ISE IRAWO IYEPE
1.     Farmer
2.     Building construction
3.     Musican
4.     Teacher
5.     Suplier
Etc
AWON EGBO IGI TI O DARA FUN IRAWO RE
1.     IRAWO AFEFE
Je eniti yio maa se Adua daadaa, ki osi maa tan Turari pupo ni igbati o baa nse Adua lowo, Maa lo Turari Adua dada ni gbogbo igba, Aseje, Ose, ati Ebu ntete maa nsise lara iru irawo yii nidiwon ti won baa nti nse adua ki won to lo

2.     IRAWO OMI
Ki won je iru Eda ti o nlo unkan ti won fi omi pipe, gegebi Hantu mumu, Obe Aseje tabi ki won maa we ose dudu. Ebu Jijo ki sise lara won, bi won baa fi one million se ebu fun iru won kole ri one naira ni ibe.

3.     IRAWO INA
Irawo ina gbodo sora fun wiwe ose ni gbogbo igba, Ohun ti o dara fun iru irawo yii naa ni Ki won maa lo Ebu ti a jo.. Ebu ni o nsaba maa sise pupo fun won ju gbogbo ogun miran lo, Awon Ogun miran naa maa nsise fun won sugbon ko dabi ki won lo Ebu

4.     IRAWO IYEPE
Irawo yii gbodo maa se Sara Daadaa, ki won maa fon awon unkan jije si ile fun awon eda ti won nse aiye iyepe, Ose Dudu ati Aseje dara pupo fun won

AWON IRAWO OJO IBI
1.     January 20 si February 18 Irawo Afefe
2.     February 19 si March 20 irawo Omi
3.     March 21 si April 19 Irawo Ina

4.     April 20 si May 20 Irawo ile


5.     May 21 si June 20 Irawo Afefe

6.     June 21 si July 22 Irawo omi


7.     July 23 si August 22 irawo ina

8.     August 23 si September 22 irawo ile


9.     September 23 si October 22 irawo afefe

10 October 23 si November 21 irawo omi

11 Novermber 22 si December 21 irawo ina

12 December 22 si Jnuary 19 irawo ile

FUN ALAYE LEKUN RERE E LE KAN SI WA LORI ERO IBANI SORO YII
08029484696 tabi 07037422552



LAIPE AO MAA SE ALAYE NIPA RERE ATI ABURU OJO KOKAN TI WON BI EDA SI AYE.
Ojo kokan ti a bi eda si aiye ni oni ohun ti o baa eda wa si aiye, Bi Ase da Aburu be naa ni Ada rere. Iwa omo ti a bi ni Monday ko le papo mo Thursday laye, Eku Oju lona
1.     OJO MONDAY
2.     TUESDAY
3.     WEDNESDAY
4.     THURSDAY
5.     FRIDAY
6.     SATURDAY
7.     SUNDAY

6 comments:

  1. Ebere Oro ti ko ba ye yin lori awon oro yii, ohun ti o ba ru yin loju ki ebere ao maa se alaye fun yin leyo kokan

    ReplyDelete
    Replies
    1. Welcome To Ewe Nje (B E N) Worldwide >>>>> Download Now

      >>>>> Download Full

      Welcome To Ewe Nje (B E N) Worldwide >>>>> Download LINK

      >>>>> Download Now

      Welcome To Ewe Nje (B E N) Worldwide >>>>> Download Full

      >>>>> Download LINK sT

      Delete
  2. Thanks so much sir, irawo Ina ni oje temi. Mofe ke tunbami se alaye lekun rere Lori ise to oni irawo Ina lese ati alaye lor ojo tiwon bimi tioje Ojo Monday. Olohun a ranyin lowo.

    ReplyDelete
  3. Eejo sir, e wo ni irawo ile

    ReplyDelete
  4. Welcome To Ewe Nje (B E N) Worldwide >>>>> Download Now

    >>>>> Download Full

    Welcome To Ewe Nje (B E N) Worldwide >>>>> Download LINK

    >>>>> Download Now

    Welcome To Ewe Nje (B E N) Worldwide >>>>> Download Full

    >>>>> Download LINK

    ReplyDelete