Monday 4 September 2017



TURARI AWORO TODAJU
Ao wa ewe awerepepe gbigbe tabi tutu, ewe wawa, iyepe mosalasi nla tabi church nla meta, Iyepe oja nla meta, Turari Lubansacara die, Turari Jawal die, Iye agbe, iye aluko, iye odidere eyo kokan, ao gun papo mo imi ojo die, pelu etu ibon gidi, ao fi orisirisi Lofinda 16 po papo ao naa saa si ategun ao gbodo saa si inu orun raaraa, ao gun kuna daadaa, ao ro sinu awo funfun olomori kan, ao maa fin ni eyin irun asuba ki orun koto yo. Pelu ase Olohun ao maa ri Opolopo Ero

TURARI AWURE
Ao waa ewe rere abo 201 rere ako 201, ao waa eyiti koluju raaraa, ao han Yaa Allahu si Ako, ao han Yaa Muhammad si abo, ao saa kofi gb e ninu orun ti o baa gbe tan ao waa iye igun 16, iye akala 16, iye agbe 16, iye aluko 16, Iye odidere 16, iyepe okun ati osa, ao gun papo ao fi turari Dandualah iyekiye po papo daadaa, ao ro sinu apo aso funfun ao maa fin ni emeta larin ose, Monday, Wed ati Thursday

2 comments:

  1. Turare Yi sise gan koda otun Sise ohunti miolero bi ki awon customer laelae kiwonma padawa pelu ebun Nla. Ewenje yio magasi ni Lola kahba

    ReplyDelete