Wednesday 25 October 2017

EBE AWON AGBA TODAJU

Ao waa epo obo aso fun fun ilaji opa, ao te aso yen sile, ao ko epo obo le lori, owo eyo 16 ti koluju le lori, odindi ataare nla kan le lori, ao lo ri mo oju ona ti won ngba daadaa fun ojo meje, lehin ojo keje ao jo, ao lo kuna, ao ma fi epo pupa la ki ato sun ni ale,

AKIYESI
Ti aba ti wu kuro ninu ile, ao ka iye owo eyo yen, ti o baa pe 16, ise ti sese ni yen sugbon ti ko ba pe 16 mo, ao gbodo lo mo ooo, oni ewu ti aba lo oo, ao lo ko danu ni

Sunday 24 September 2017

ORORO IPARA ANU TODAJU
Ao gun ewe imunle die, ewe lapalapa funfun die, ata ijosi meta, epo obo die pelu epo igi nla die kuna daadaa, ao daa sinu Olive oil ao da lofinda orisi meta si die die, ao maa fi para, Odaju samu

Ewe Nje (B E N) Zones
Aki gbogbo awa Zone kokan ni ipinle kokan wipe aku dede iwoyii, Olohun ko ni jeki emi ati eyin waa wo iran laye, gbogbo waa pata lao gbe rere se laye. Amin.
oro wa da lori awon zone kokan ti a ti gbe kale ni ipinle kokan ni all over the world, laipe yii ao maa mun date ti afe gbe meeting ojukoroju kale ni ipinle kokan, Ninu Meeting yii ao ko Form Egbe waa si Zone Kokan, ki gbogbo Awon ti won baa fe ko ipa ninu Meeting yii toju 2 copies of there Passport, okan yio wa lori form ekeji yio waa fun Membership ID card.
Lagbara Olohun ki Ose yii topari ao maa Announces Agbegbe ti ati fe bere Meeting yii ni ilu Eko. Anfani po pupo lori meeting yii, Opo Enia ni won nilo awon asiri kan toje wipe gbogbo ibiti won baa de lati gba awon iru asiri yii EBU ni won ngbe le won lowo pelu owo topo, mofi Olohun Bura meeting kekere ti ase ni arin ara wa lana, Asiri orisi 35 ni mo gba ni Ano lowo awon External people ti won je agbalagba ti won bawa joko meeting lana, ti asi tun dan bi Mefa wo lana yen naa, koda lara awon asiri kan ti a ri gba ni wipe
BI ONA BADI TI AIYE BADE OWO ENIA
Epo Obo, ao gun kuna ao fi iyo po papo, gbogbo eniti o baa nso wipe ogun agbana nda ohun lamun etc ki abu die si owo ki amaa fi owo keji raa titi yio fi wo ile
ninu awon Asiri ti emi tun rigba lana
1. Ado Atona todaju yato si eyiti won maa nfi Owo gbesoke, ti won o ma paro wipe o dide fun ara re, koda atun danwo lana tosi daju
2. Ogun Atude todaju,
3. AKOYE ASASI todaju
4. Ipese Ado gbe Adomin Eiye wonu Eiye
5. Olugbohun ti won ma nfi npa Adie, tabi anything koda o le pa Malu, omo odo agba iba yin o
6. Awon Isora lorisirisi
walahi o ku die bayi ao baa gbagbe wipe awa se meeting lana toripe gbogbo awa ti a waa ni meeting lanaa ntu ara sile ni, inu awon agbalagba to wa pelu wa ndun ni, ti won nsi ndan ise wo fun waa, Ha! asiri nbe, koda molero pe awon baba waa ti gbe agbara lo tele ni, asiri nbe.
nidi eyii inu wa yio dun bi ebaa le darapo mo egbe Ewe Nje (BEN) Tokan tokan.
Ewe Nje BEN
kunfayakun

Saturday 23 September 2017

IRISI SURATUL YASIN TODAJU
Ao han Suratul Yasin eyo kan pere, sugbon ni eyin Ayah Kokan ao maa han Lakodijakum rosulu...... de ipari, be lao se han titi ao fi pari hihan re, ao fo ao waa ewe mafi owo kan omo mi, ao jo pelu Kalamun ti afi han Surah yii ati odindi ataare kan, ao waa fi hantu yii mun ebu yen lekan soso. bi ota baa pe one million ti won baa ti npe ori waa ni ibi beni ibi naa yio maa baa won lesekese, ti inira baa poju fun won, ti won baa jewo ese won ki adari ji won toripe bibe ko, eni naa yio ku ni. odaju. Ti abati mu hantu yii tan yio fe se waa bi iba sugbon kosi iyonu, ao gbodo lo ogun si ti ara waa baa nse bakan bakan toripe bi aba lo ogun si, Otaa naa koni ri inira kankan ti won baa nsa ogun siwaa, ti iniraa baa ti nba ota waa bi o baa lo ogun koni sise. odaju samu
ASIRI TI A NFI NKO ILE SI ORI ILE
Asiri ni eleyi ki se ogun raaraa, asiri sini baba ogun koda iyalaya ogun, Afi ele ki gbogbo Awon Admistration egbe Ewe Nje pataati ni ilu nla mejeji ti atise Meeting loni, apadabo meeti9ng waa yio jasi irorun fun gbogbo awa ti awaa ninu group yii pata.
Ao waa Ile ikan to gaa daadaa, ao ge ori ile won waa si ile ao fi omi po ko ki daadaa, ao waa eyin ororo meta, ao fi iyepe ikan yii mo ara eyin meteta ti aye kankan ko gbodo han sita raaraa, ao gbe lo si ori ile naa ao gbe ile naa ko jin die, ao waa gbe ohun ti amo pelu ile ikan yen si inu koto naa, ao waa baa wi gbolohun wipe
OHUN RE
Ati ojo ati erun ni ikan nmo ile tire, ki awa egbe ewe nje tokan tokan ko ile wa ni odun yi ni kia kia, toripe, omi ki po lojo ki ikan maa mo ile tie, ki asiri awa omo egbe yii bo ni kia kia ki affi ko ile yii ni kiakia. ao waa bo mole,
walahi ko ju baayi lo, pelu Ogo Olohun Ao ri owo ko ile yii nji kia kia,
ti ko baa daa yin loju, Efun mi ni 4 plots ninu ile yin ki ndan asiri yii wo ni ibe hahahaha odaju walahi

Wednesday 20 September 2017

ADURA TIAFINKOJU EYIKEYI ISORO YALA OGUN OTA, OGUN IDILE, ABI EYIKEYI OGUN AIFOJURI TONBA OMO ENIYAN FINRA TIKOJEKI ONI ILOSIWAJU NINU IRIN AJO AYEERE
TI OBATI JA EWE TOSITI WA EGBO TOJEWIPE OJU KAN NAN LONJASI, IWO OMO IYAMI DAKUN NI IGBAGBO KOSIGBIYANJU ADURA YII WOO HNMM NINU EPE NINU ADURA WAASEKAN
Aowa aso pupa, aoran ni deede sokoto ewu, ati fila, tobawadi deede agogo mejila abo oru (12:30a Aose Aluwala Aoyan
Nafilah Rakah 2, Fathia 99 Lori iduro kookan, aonikaa surah kankan leyin re, aowa salamo, sugbon origun mereerin laoyan nafilah meji meji yen sii, aomaasalamo ni origun kookan, leyin salamo aodojuko kiblah (gabasi) aomu tesbah aose
ISTIGFAAR........1000
ASALATU ALA NABIYYI........1000
HASBUNALAH WANIMOL WAKEEL........4
050
Aodide aolosun, aosebee fun ojo meje, leyin ti ojo meje bape..........Aodin akara elepo pupa, abi kapa adire akuko totobi daada, aofise sahara,
hnmmm Ti oro eeyan kobatiidebi wipe kofeeni ojutu Mon kodakun komase iseyii ooo, bi iseyii se rora kere mon, wonmanfi pa ota tobako tikofeejawo ninu oro aye yan nii ooo,,, aiye oni muwa o, gbogbo Lao segun awon ota wa ola anobi Mohammad,,, ameen.

Omo Odo Agba one

Wednesday 13 September 2017

ADUA FUN INTERVIEW TABI EXAMINATION 
Ao se aluwala, lori ijoko ekan pere ao saa يا ولي ١٩٩٩٩ ao ma sa Yaa waliyu 19,999lori ijoko ekan pere, ti aba ti pari adua yii ao pa akuko adie kan fi se sara, ojokojo ti aba ti ni exam tabi Interview ao maa saa Yaa Waliyu 150, ao si tun se sara lehin exam tabi Interview naa