Saturday 2 September 2017

ISORA ATURA AWORO ARIMOLE NINU ILE WA
Ao gbe ile ko fe die si arin ile tabi enu ona ile waa, ao waa lobu iyepe iwaju ita gbangba ao da sinu koto naa ao waa te erupe yii ni ifa Ejiogbe, qo fi Ori si inu Ifa naa ao bu iyo si ao waa daa epo pupa le lori, ao se opolopo Adua si bi abase fe, ao fi unkan bo ori Ifa naa ao waa da iyepe bo mole ao re pelu cement pa. Odaju

2 comments:

  1. Welcome To Ewe Nje (B E N) Worldwide >>>>> Download Now

    >>>>> Download Full

    Welcome To Ewe Nje (B E N) Worldwide >>>>> Download LINK

    >>>>> Download Now

    Welcome To Ewe Nje (B E N) Worldwide >>>>> Download Full

    >>>>> Download LINK

    ReplyDelete
  2. Konitan nibe

    ReplyDelete