Friday 1 September 2017

OSOLE TODAJU
Igun Oye kan, ori oka to ni ase lenu meta ori ere toni ase lenu meta tosi tun tobi pelu, egboigi ajeobale, odindi ataare nla meje, ki ato jo awon egboigi yii, ao gbe epo ati oti losi orita meta adugbo waa, ao daa epo sile ao tun taa oti sile, ao lo si idi aro ti ati fe jo ogun yii ao tun se be pelu ao waa jo awon unkan won yii, ao lo kuna daadaa, ao ma fi mun eko gbigbona, ao koko so ori sinu eko yen ki ato da ebu yen die si, ti ori yen baa ti yo sinu eko yen ao waa sese da ebu si ao ro papo ao gbemu, ki akoko se be fun 7 days, lehin 7 days ki a maaa lo ni Emeji lose, Monday  ati Thursday. Lasiko ti a nlo Ogun yii ao maa ri owo daadaa

No comments:

Post a Comment