Friday, 1 September 2017

ASIRI TI OUNJE KONI FI MA WON WAA NINU ILE
Ao han Suratul Nasir  Eyo kan pere ao  ti abati de ibi Afuwajan yen ao para ibe ni igba 101 ao waa pari Surah yen dele, ao wa ijesi adie to kun daadaa, ibiti adie maa nje ounje si ni orun re, ao jo pelu ewe awerepepe die  ao lo kuna ao fi se gari tira yii, ao waa iwe akuko adie to tin nko daadaa, ao ki tira yi si ninu ao di lowu funfun ao fi ko enu ona waa ao si maa saa Surah yen ni igba 1000 lojojumo tabi 313, won yio maa gbe ounje fun wa lona kona.

Akiyesi
Adie ti alo iwe re naa lao lo ajesi re, ogbodo je akuko nla toti gbo daadaa, ti a baa fe la iwe yen ao gbodo ko idoti ibe kuro, ao ki tira yen bo be ao di lowu funfun, owu funun naa lao fi i tira yen. Odaju

No comments:

Post a Comment