AFORAN TODAJU
Ewe Irosun mesan fun okunrin meje fun Obinrin, ao to won papo ao fi owu funfun di ao lo di mo igi ti ategun fi maa gbe jo ao mun obi alawe merin eyikeyi color dani ao yo awe kan ninu obi naa ao ju si enu ao maa pe ofo bayi wipe
OFO RE
Ejo nla ni muni mo ode ogbon
Oran nla ni muni mo ode osugbo
Oran ti obi alawe meta ba da, orun alawe merin lati nbi,
ti apawa ba san ni igbo, igi imi ni nteri gba, oran ti Lagbaja omo Lagbaja ba da ki won ma fi bi, Adua, ao ma je obi yen leyo kokan ao maa se aduq ao maa tu si eyiti aso mo igi yen
No comments:
Post a Comment