Saturday 23 September 2017

ASIRI TI A NFI NKO ILE SI ORI ILE
Asiri ni eleyi ki se ogun raaraa, asiri sini baba ogun koda iyalaya ogun, Afi ele ki gbogbo Awon Admistration egbe Ewe Nje pataati ni ilu nla mejeji ti atise Meeting loni, apadabo meeti9ng waa yio jasi irorun fun gbogbo awa ti awaa ninu group yii pata.
Ao waa Ile ikan to gaa daadaa, ao ge ori ile won waa si ile ao fi omi po ko ki daadaa, ao waa eyin ororo meta, ao fi iyepe ikan yii mo ara eyin meteta ti aye kankan ko gbodo han sita raaraa, ao gbe lo si ori ile naa ao gbe ile naa ko jin die, ao waa gbe ohun ti amo pelu ile ikan yen si inu koto naa, ao waa baa wi gbolohun wipe
OHUN RE
Ati ojo ati erun ni ikan nmo ile tire, ki awa egbe ewe nje tokan tokan ko ile wa ni odun yi ni kia kia, toripe, omi ki po lojo ki ikan maa mo ile tie, ki asiri awa omo egbe yii bo ni kia kia ki affi ko ile yii ni kiakia. ao waa bo mole,
walahi ko ju baayi lo, pelu Ogo Olohun Ao ri owo ko ile yii nji kia kia,
ti ko baa daa yin loju, Efun mi ni 4 plots ninu ile yin ki ndan asiri yii wo ni ibe hahahaha odaju walahi

1 comment:

  1. edakun se ao ma eyin metata papo ni abi ao po leyo kokan? eseun

    ReplyDelete