Sunday 3 September 2017

AGBELEPOTA ISORA ORUN
Ao han Suratul Masad 33 si ara Aso funfun ilaji opa kan pelu biro pupa, ao gbodo bere pelu bismilahi Rahamoni ROHEEM RAARAA O. Aoo bu iyepe Sare lona meje ao da papo, ao gun kuna daadaa, ao waa ewe to hu jade lori sao sa kofi gbe daada ao lo ohun naa loto kuna daadaa, , ao waa te aso ti a han Tabatiyada yi si abe pillow waa fun ojo meje ao maa fi ro ori sun, lehin ojo keje ao naa aso yii si iwaju waa, ao waa koko dq iyepe sqre yen le lori, ao waa sa suratul Masad 1000 ni iwaju aso yen, ti aba pari sisa re tan ao waa fon ewe ti alo yena si lori, ao waa di pelu owu funfun daadaa, ao waa gbe lo si inu igbo kan ao gbe ile ko jin ninu igbo yen, tabi ki a lo rimo anywhere, ti abati gbe Asoyii sinu Koto Ti Agbe yii, ao waa so wipe, Eyin isinku Orun o, Emi lagbaja omo lagbaja ni mo  beyin lowe si Okunrin obinrin, Omode ati Agba ti nba npe ori minibi, Gbogbo ohun aburu ti won bani ko ma semi ni ki o maa se won ni kiakia, Eyin isinku Orun o ewa maa gbe ija emi Lagbaja Omo Lagbaja ja, Ema da awon Otami lamun loju  orun ati loju Aiye, Ki idamun ba gbogbo awon Ota mi, ti aba ti so ba yii tan, ao fi iyepe bo mole, ao sare kuro ni ibe kia kia, ao si gbodo wo eyin titi ao fi dele, ao maa gburo Ese enia pupo leyin waa sugbon kosi aburu, Won ti wa lenu ise won ni yen. Ti won ba mun oruko yin losi odo awon Ika, tabi ti won ba bere Agbara yin, Won aje ko yewon wipe Agbara orun ni eniti o ba se ise yii nlo,

AKIYESI PATAKI
Ti abati fe bu iyepe ori sare kokan lao ma so wipe, isinku orun o oo emi lagbaja omo lagbaja fe bu iyepe ori iboji re lati ffi seise Isora Agbelepota, beni ao se maa so ti aba fe ja ewe ori iboji naa, ti ao baa so be isnku orun yio maa telewa kakiri ni o, koda ti won ba le tele wa wole, won yio maa da inu ile ru ni. Agbodo ma so awon gbolohun yen ki ato bu iyeepe tqbi ja koriko ori iboji oku naa.

Lehin ti aba de ile pada lehin ibi ti alo bo aso yen mo, ao pa adie akuko kan ati abo kan ao fi se sara fun awon omode awa ni si gbodo je ni ibe, eleyi tumo si pe, awon Isinku ti won ntele wa bo, afi paroko fun won wipe Ki won maa bawa pa otaa Okunrin ati Ota Obinrin ti won nba npe ori wa ni ibi. Ti aba ti se be oti pari, ti ao ba sebe won yio ma tele wa kakiri ni, won asi ma dawa lamun loju orun.

No comments:

Post a Comment