Wednesday 13 September 2017

TURARI TI A NFI NSE ADUA FUN AWON ENIA TI WON WAA NI OKERE
Oga gbigbe 16, iye agbe 16, iye Aluko 16, ikodie 16, iye lekeleke 16, Ewe pawondaibida sobi dire ao gun papo daadaa, ao ko won sinu aso funfun, ao waa jaa ewe lapa ti kolu 16, ao han Suratul Fatiha kokan si ewe kokan, ao jaa ewe Bomu bomu 16 ao han Suratul Fatiha lati oripodi si ewe kokan, ao gun mejeji po pelu imi ojo die, ati etu ibon die, ao saa si ategun, ao waa da mejeji papo, ao ro papo daadaa, ao da si inu apo aso funfun ko gbodo kanle mo, ao maa fin ninu ina laro kutu kutu ti aba fe fi se adua fun enia ti ona re ba jin,

Ao waa Apere kan, ti aba ti fin turari yii ao da apere yen bo mole, ao waa joko si iwaju re ao maa saa Suratul Fatiha 92 ti aba saa tan ao si apere yen ao waa toro ohun ti afe fun eni naa. Lagbara Olohun Adua naa yio gba ni kiakia.

No comments:

Post a Comment