Thursday 7 September 2017

OLUGBOHUN TODAJU

Ao han Suratul Yasin meta, okan Ariran, Okan Afoju, Okan Aditi, sugbon gbogbo igba ti aba ti de ibi ini amantum birobikum huntsman ao maa para ibe ni igba 1111 ti o ba ti pe 1111 ao waa pari Surah naa, ao fi omi die fo hantu kokan si aye ototo. Ewe Ogbo ti ko luju 21, ao han Yaa Jabar si ewe kokan ao sa kofi gbe daadaa ao gun kuna aopo pelu ose dudu ti o le gba inu iwo Malu kan, ao fi omi hantu Ariran po papo daadaa ao tun fi Ariran naa po daadaa, Lehin naa ni ao fi Aditi po daadaa ao gbodo fi gbogbo re popo lekan soso ao to tele ara won bi ase ko si ibe ni.ao fi odindi Ataare kan, ati Ako okuta meta sinu iwo malu yen, ao ki oga oye bo ti yio gbe ori soke, ao ko ose yen le lori, ao fi aso pupa bo lori,, ao gbe si ori ajah fun ojo meje, lehin ojo keje lao to de ibe lo mun, lati igba ti ati lo gbe si ori ajah yen lao ti maa saa  ini amantum birobikum huntsman 1111 fun 7 days ti aba pari re lojo keje, ojo kejo lao le gbe kuro lori ajah ao gbe wonu ile ao fun ni oruko ao si baa se adehun wipe Ti mo baa ti pe Oruko re ni ki o to jemi oo, ao fun loruko naa, ti a baa ti fe lo ao pe oruko re lemeta ao fi ahon kan ao so ohun ti aba fewi. Odaju


ise yii waa lati odo shaik mi, Al Bayanah ni ilu ninja

No comments:

Post a Comment