AWORO TO DAJU
Ao waa candle funfun 16 lona marun, lara candle
kokan ao maa fi Abere han Ayah yii si gbogbo ara candle kokan ti aye Kankan
koni han lara candle naa, Inahu ala rojeehi lakodiru, ao han si gbogbo candle
yen lara pata, ao waa di 16 papo pelu owu funfun, ti yio fi je 16 lona marun,
ao waa ako alangba marun. abo naa marum, alangba naa je mewa pali Sugar st Louis kan, ao gbe ile si
igun mererin aye ti afe gbe ise yii si ati arin gbungbun aye naa, ao fie yin
Bobo kan lele, ao da ponri de lori, ao gbe candle yen le won lori loro ti yio
koju si oke, ao fon suger St Louis 16 si inu koto naa, ao daa iyo cup kan si
pelu oyin agolo milk kan, be lao se se si gbogbo igun iyoku ao se be naa ni
arin, ao waa bo si egbe igun ibiti a ri unkan yen mo ni egbe otun, ao pe irun
Azubah toni ASOLATU KHERU MINA NOMI si igun akoko, igun ekeji ao pe iru ago
meji si, igun eketa ao pe irun ago merin si, igun ekerin ao pe irun ago meje si
Igun Ikarun ao pe irun ago mejo si, ti aba ti fe maa pe irun kokan ao maa
daniyan irun ti afe pe, ti abaa ti npe irun kokan ao maa bo si arin ile ti a ri
elekarun mo ao maa se IKHAMO ni ibe, ti oba dori irun elekarun, ti aba tip e
tan ao se IKAMOH ao waa da iyepe bo won mole.Bi ogo baa nje ti Olohun ti won
baa ti npe irun kokan laye beni Olohun yio maa dari awon enia waa raa gbogbo
ohun ti a nta. Iru aworo bayi daa ni aye ti won baa ti nta Ounje,Oja, Ile ise
Nla, EtC
Ejowo mini itumo bobo sir
ReplyDeleteEjowo kini itumo bobo sir, atiipe IBO latileri a won iwe naa ra
ReplyDelete