Monday, 4 September 2017



OSOLE AFARO
 Igun kan ori akala kan odidi agbe kan odidi aluko kan odidi odidere kan odidi atare 16 ti abafejo ogun yii aofi epo pupa ro ekuru ki awon omode je aotun fon si ayika wa aomata oti si lori inan tiyio fijo tan aomafi omi aye lo laro kutuku


AGBO AWEBIDANU
Ikoko titun aogbe kanan aowa ju ori nlanla kan sinu re tobati yo aoju epo obo kan sinu retiyio din epo yan aowa bomisi aoju ako alangba oye kan si aose jinan aowa yo omiyan sibikan aofi ose isale yii We pelu Kainkain titun Osere egbo tude die ata ijosi mesan epo obo die werejej mesan aogun mose dudu iwe ekan aolofi we agbo yii lekan aowa fokoko ati agbo yan sorita tabi akitan

2 comments:

  1. Ise agbo yi kofe ye mi oo se ama fi omi si ki ato fi oori sini abinibo lati re omi?

    ReplyDelete