Friday 8 September 2017

ASIRI SURATUL FATIHA
FUN AWORO
ao han 41, ao gbo ewuro pelu omi ao fi fo hantu yii ao daa sinu ado ato ao daa iyo ati ori si, ao so ko si enu ona waa odaju

FUN ASINA TODAJU
Ao han ni igba 313, ao fo si ibi kan, ao waa ewe Ela die, Ewe Awerepepe die, ao lo pelu iyere die, ao fi se Ahon malu tage si mesan je fun Okunrin meje fun Obinrin, Ti aba ti fe je ki ato je eyo kan ninu ahon yen, ao ka Ipari Suratul fatiha lemeje, صرطالذين انعمت عليهم غير المغضوب عليهم ولا الضل لين be lao se maa kaa titi ao fi je tan

FUN KI OWO MAA WON WAA
Ao han Suratul Fathia 41 si opon ola ni igba Meta 41x3 si ike ototo, ao waa igbin to tobi meta, ao fi okan se igbin yii pelu eyin meta. Ti o ba jina, ao w ewe aje die, ewe Orijin die, ewe awerepepe die gbogbo ewe yii gbodo je ojoo, ao lo meteta pelu ata ijosi die, ao wa fi hantu keji se awon igbin ati eyin ye je lodidi ni o, iyo epo gbodo wa ni ibe, ti o baa jina ao koje ao waa mun eleketa le lori. Odaju

No comments:

Post a Comment