Thursday 7 September 2017

ISE YII JE ISE NLA TI O MAA NTUN IGBESE AIYE ENIA SE


Ejinrin tutu, adie abo toti bimo ri dudu, eyin adie ibile 16, atare odidi 16, eye onbe 16, iye igun 16, ewe ako rere tojo, ewe bomubomu ati ese re topo tojo, eye kowe meta, aso awon agba meta, aso egungun die, egbo tude topo, epo obo topo, igi nla topo, itanna ibepe ako topo tojoo, ao ko gbogbo won sinu ape, ao wa du eje penpeye ako funfun si lori, ao wa gbe kana, ao fi epo pupa yipo aro, taba jo tan, ao Di mo aso egungun tabi aso dudu, funfun, pupa, ao so ko soke, ao wa mafi epo pupa LA lalale, oti lo laro laro.

No comments:

Post a Comment