IWE EGBE EWE NJE VOLUME 2
Iwe Egbe Ewe Nje Volume 2 ti waa ni ori ate bayi fun gbogbo eyin Ololufe egbe Ewe Nje, awon ibiti etile ri awon iwe wa raa
1 Ibadan
2. Eko
3. Oyo
4. Igboho
Epe awon number won yii fun ekun rere alaye
07037422552
08034151751
07067124318
08038081390
08125703383
07066504892
Thursday, 31 August 2017
Wednesday, 30 August 2017
OLUGBOHUN ADURA TODAJU
Ao wa iwo malu kan, oga oye kan, eyo ataare mesan, ewe esisi funfun, ewe aragba, ao gun ewe mejeji papo mo ose dudu, ao ki oga oye yen bo inu iwo malu naa ti yio yo ori soke, ao koko ko eyo ataare mesan si inu iwo yen ki ato ki oga yen si, ao ko ose ten fi bo lori, ao maa fi kan enu fi se adua lorisirisi. Koda ti abani Enia ni ilu ibo miran ti o baa nri awon walah kan, ki afi se adua fun, lagbara Olohun won yio maa ri gbigba adua naa ni kiakia

EPE TODAJU
Iwo eran agbo ibile ti won pa lojo odun ileya, eyokan, ojo ti aba fe se ise yii lao lo ja ewe ewuro ojo, ao lo ra orogbo lojo naa orogbo kan ni o, ao gun mo ose dudu ao kosi inu iwo eran yen. Ao fi aso pupa bo lori ao ma pe ohun si bayi
OHUN RE
ojojumo ni ikoro nba ewuro, ojojumo ni ikoro nba orogbo, ojo odun ni ikoro nba Eran Agbo ki ori bayi bayi fun lagbaja omo lagbaja ao fi enu kan so ohun ti abaa fe so. Ti a baa lo epe yii fun odun kan, koda bi ao baa gbe epe yii lowo mo ti abaa fi enu se epe ni kia kia ni yio maa se

Monday, 28 August 2017
OSOLE TODAJU
Okete tapa loojo ti eje kojade larare kan ewe abo 201 obi ifin alawe merin kan ipa alawe merin kan, odidi atare kan epo Igi nla die ojoo lewe abo yan naa gbodo je aowa ki ewe yan bo lati enu de ikun re aojo pelu atare aowa lo lori bench ijoko ori apoti Laoko ese wa mejeji lelori taba nlo aowa ro sinu sere aogbe sinu asunwon aso funfun aogbe kobiti oju meji konitiri afi ojuwa nikan ao koko teni ejiogbe lori beach yan taoro itan resi kato rosinu seere yan
Ohun re ni
oso kerukeru eru eleru ni okete nru tifi se ola ki olo gbe owo olowo fun mi wa loni kinfise ola adura aomafi fo eko tutu mu loseose
Osole owo
Ori ofafa tonirun eyin adie mewa atare kan afomo ewe botuje funfun tiko kanle aojo po aofi mamu eko tutu lemeji larin osun kan

Subscribe to:
Posts (Atom)
-
IFERAN GBOGBO ENIA TODAJU Ewe Awerepepe, ewe Taba ibile, Igbo mimun, ori ijapa, ao gun kuna daadaa, ao da sinu lofinda eyikeyi ao maa fi pa...
-
ASEJE OWO TODAJU Ao han Suratul Wakiah 313, ao wa afomo iyalode funfun tutu 313 ao maa han Yaa Fatahu si ara ewe kokan, ao waa lo ewe y...
-
ISORA ATURA AWORO ARIMOLE NINU ILE WA Ao gbe ile ko fe die si arin ile tabi enu ona ile waa, ao waa lobu iyepe iwaju ita gbangba ao da sinu...