Monday 28 August 2017

 OSOLE TODAJU
Okete tapa loojo ti eje kojade larare kan ewe abo 201 obi ifin alawe merin kan ipa alawe merin kan, odidi atare kan epo Igi nla die ojoo lewe abo yan naa gbodo je aowa ki ewe yan bo lati enu de ikun re aojo pelu atare aowa lo lori bench ijoko ori apoti Laoko ese wa mejeji lelori taba nlo aowa ro sinu sere aogbe sinu asunwon aso funfun aogbe kobiti oju meji konitiri afi ojuwa nikan ao koko teni ejiogbe lori beach yan taoro itan resi kato rosinu seere yan

Ohun re ni
oso kerukeru eru eleru ni okete nru tifi se ola ki olo gbe owo olowo fun mi wa loni kinfise ola adura aomafi fo eko tutu mu loseose

Osole owo
Ori ofafa tonirun eyin adie mewa atare kan afomo ewe botuje funfun tiko kanle aojo po aofi mamu eko tutu lemeji larin osun kan

No comments:

Post a Comment