Wednesday 30 August 2017

EPE TODAJU
Iwo eran agbo ibile ti won pa lojo odun ileya, eyokan, ojo ti aba fe se ise yii lao lo ja ewe ewuro ojo, ao lo ra orogbo lojo naa orogbo kan ni o, ao gun mo ose dudu ao kosi inu iwo eran yen. Ao fi aso pupa bo lori ao ma pe ohun si bayi

OHUN RE
ojojumo ni ikoro nba ewuro, ojojumo ni ikoro nba orogbo, ojo odun ni ikoro nba Eran Agbo ki ori bayi bayi fun lagbaja omo lagbaja ao fi enu kan so ohun ti abaa fe so. Ti a baa lo epe yii fun odun kan, koda bi ao baa gbe epe yii lowo mo ti abaa fi enu se epe ni kia kia ni yio maa se

3 comments: