Saturday, 2 September 2017

ASETA TOBURU TODAJU
Ao han SAFI ti yio pe daadaa, ao waa ako alangba kan ti afi egba pa, ao fi tele koko isasun dudu kan, ao ja ewe akoko ojo, ewe ajeobale ojo, ao da sori Ako Alangba yen, Ao fi omi topo daadaa fifo Safi ta han yen, ao daa sori awon egbo igi yen, ao fi se ko jina daadaa, ao yo omi yen si ibi kan, ko fi tutu die.

OSE RE
Ao han Safi kan, Ewe Ajeobale to jabo fun ara re to siju si oke, epo Obo die, ao gun po, omi hantu yen lao fi po papo, ao ko ose yi sinu igba oni koko, ao fi Orogbo kan gun lori, ao bu die ni ibe fi we agbo yen. Ti aba fe se fun enia ao se agbo yen ose yen lao ma bu fun won fi we ni Ale ki ato sun.

No comments:

Post a Comment