OSE ASETA TO BURU JAHI
Ao han Khaf meje, Ewe Ewuro ojo, Ewe Akonimora die, ao gun lose dudu, Omi Khaf yen lao fi po papo daadaa, Ao waa obe kekere tuntun kan ti koni eeku ni idi, ao fi gun ose yen legbe, ao fi ako okuta gun ose yen ni arin ti yio jin wole daadaa, ao paa adie akuko kan ao ro eje yen si inu iho yen, ao fi omori igba yen de pada, ao lo gbe pamo fun 40 days, ao gbodo de idi re ooo, odi eyin 40 day ki ato de ibe ooo, ao gbodo siwo mo lehin ti abati de paa, ao lo ti mo inu cupboard ni, tobadi eyin 40 days ao maa fi obe yen bu sori kehin kehin lati fi we.
Ti Awon Ota baa nsa siwa, Awon ruhu ni won yio fi obe gun ota naa paa, Ao gbo sun ekun bi aba gbo ofo enia kan ni idile baba tabi idile iya ni asiko ti a nlo ose yii. Odaju

No comments:
Post a Comment