TURARI AGBELEPOTA ATI ASINA
Ao waa ewe afeloru tutu ti koluju To po die, ao waa han
Suratul Fil 71, ao fi omi gbo ewe yen daadaa, ao fi omi ti agbo yen fo hantu
yen, ao waa gun sakiti ewe afeloru yen pelu, kaji dudu ati pupa, Ewe Etiponola,
Ewe esisile ati epo obo die, ao fi omi
hantu yen po papo, ao saa si ategun, ao maa fi fi saa Suratul Fill 1000
TURARI TI A MAA NFI NLE EMI
BURUKU KURO NINU ILE
Ewe Ajeobale, Epo Obo die, Ataa Ijosi die, kafura pelebe
die, imi ojo die, ao gun papo, ao maa fin sugbon ao gbodo duro si enu ona ni
igbati a baa nfin lowo, a gbodo jade sita ni. Ti enia kan baa duro senu ona ni
wakati ti a nfin lowo, tie mi kan baa fe jade, odaju wipe ti o baa kolu eniti o
duro si enu ona, eni naa koni pe ojo keje laye. Ao gbodo duro ni enu onaa
raaraa. Ti abati bu si ina ale joko tabi ki a jade, ao si ilekun sile ni. Odaju
saka
TURARI
ISORA TODAJU
Ori oka kan to lase lenu, Ewe apada, pupo, iyepe ori sare Opolo
gbigbe meta, Eku asin meta, ewe Mafowokan omo mi ati ewe kinlomafimise, ao gun
ni turari, pelu imi ojo die, ao maa fin lojo Thursday nikan
TURARI AWURE SURATUL TOHA
Ao wa Bomun bomun ni iye Addad suratul Toha, ao maa han Ayah suratul
Toha yii kokan si ara ewe kokan titi yio fi pe iye ti Surah naa je ao sa kofi
gbe daadaa ninu orun, ao waa Egun abubutan, Egun Esin die, Ewe wawa, Emo
aberodefe, Lofinda Tafahul Jinn ao gun gbogbo re papa,ao fi Lofinda yen po papo
daadaa,ao ko sinu apo aso funfun, ao so ko si eyin ilekun waa, ao maa fin ni
idaji kutukutu pelu sisa Suratul Toha 7. Ao koko fin fun 7 days be, lehin 7
days ao maa fin ni ao ma fin ni Monday and Thursday. Ti Olohun baa ti bo asiri
daadaa, ao paa Agbo funfun kan fi se sara Lodun naa.
No comments:
Post a Comment